quranm◉

Súrá Yunus 10:1

الٓرۚ تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱلۡكِتَٰبِ ٱلۡحَكِيمِ ﴿١﴾

◉

Ìtumọ̀

’Alif Lām Rọ̄. (Allāhu ló mọ ohun tí Ó gbàlérò pẹ̀lú àwọn háràfí náà.)Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah Tírà tí ó kún fún ọgbọ́n.2
— Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

◉ Súrá · ∞