quranm◉

Súrá Yunus 10:47

وَلِكُلِّ أُمَّةٖ رَّسُولٞۖ فَإِذَا جَآءَ رَسُولُهُمۡ قُضِيَ بَيۡنَهُم بِٱلۡقِسۡطِ وَهُمۡ لَا يُظۡلَمُونَ ﴿٤٧﴾

◉

Ìtumọ̀

Òjíṣẹ́ ti wà fún ìjọ kọ̀ọ̀kan.Nítorí náà, nígbà tí Òjíṣẹ́ wọn bá dé, A óò ṣèdájọ́ láààrin wọn pẹ̀lú déédé; A ò sì níí ṣàbòsí sí wọn.
— Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

◉ Súrá · ∞