quranm◉

Súrá Al-Mutaffifin 83:17

ثُمَّ يُقَالُ هَٰذَا ٱلَّذِي كُنتُم بِهِۦ تُكَذِّبُونَ ﴿١٧﴾

◉

Ìtumọ̀

Lẹ́yìn náà, wọ́n máa sọ (fún wọn) pe: “Èyí ni ohun tí ẹ̀ ń pè ní irọ́.”
— Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Àwọn kókó · Àyá

◉ Súrá · ∞