quranm◉

Súrá Al-Mutaffifin 83:31

وَإِذَا ٱنقَلَبُوٓاْ إِلَىٰٓ أَهۡلِهِمُ ٱنقَلَبُواْ فَكِهِينَ ﴿٣١﴾

◉

Ìtumọ̀

Nígbà tí wọ́n bá sì padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn wọn, wọ́n á padà tí wọn yóò máa ṣe fáàrí.
— Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

◉ Súrá · ∞