quranm◉

Surah Al-Qadr transliteration

◉ Súrá · ∞

97:1

إِنَّآ أَنزَلۡنَٰهُ فِي لَيۡلَةِ ٱلۡقَدۡرِ ﴿1﴾

Transliteration: Inna anzalnahu fee laylati alqadri

Translation: Dájúdájú Àwa sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ nínú Òru Abiyì.1

97:2

وَمَآ أَدۡرَىٰكَ مَا لَيۡلَةُ ٱلۡقَدۡرِ ﴿2﴾

Transliteration: Wama adraka ma laylatu alqadri

Translation: Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Òru Abiyì?

97:3

لَيۡلَةُ ٱلۡقَدۡرِ خَيۡرٞ مِّنۡ أَلۡفِ شَهۡرٖ ﴿3﴾

Transliteration: Laylatu alqadri khayrun min alfi shahrin

Translation: Òru Abiyì lóore ju ẹgbẹ̀rún oṣù.

97:4

تَنَزَّلُ ٱلۡمَلَـٰٓئِكَةُ وَٱلرُّوحُ فِيهَا بِإِذۡنِ رَبِّهِم مِّن كُلِّ أَمۡرٖ ﴿4﴾

Transliteration: Tanazzalu almalaikatu waalrroohu feeha biithni rabbihim min kulli amrin

Translation: Àwọn mọlāika àti Jibrīl yó sì máa sọ̀kalẹ̀ nínú òru náà pẹ̀lú àṣẹ Olúwa wọn fún gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan.

97:5

سَلَٰمٌ هِيَ حَتَّىٰ مَطۡلَعِ ٱلۡفَجۡرِ ﴿5﴾

Transliteration: Salamun hiya hatta matlaAAi alfajri

Translation: Àlàáfíà ni òru náà títí di àsìkò àfẹ̀mọ́júmọ́.

Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download