quranm◉

Surah Al-Kawthar transliteration

◉ Súrá · ∞

108:1

إِنَّآ أَعۡطَيۡنَٰكَ ٱلۡكَوۡثَرَ ﴿1﴾

Transliteration: Inna aAAtaynaka alkawthara

Translation: Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.

108:2

فَصَلِّ لِرَبِّكَ وَٱنۡحَرۡ ﴿2﴾

Transliteration: Fasalli lirabbika wainhar

Translation: Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).

108:3

إِنَّ شَانِئَكَ هُوَ ٱلۡأَبۡتَرُ ﴿3﴾

Transliteration: Inna shaniaka huwa alabtaru

Translation: Dájúdájú, ẹni tó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn.

Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download