عَبَسَ وَتَوَلَّىٰٓ ﴿1﴾عَبَسَ وَتَوَلَّىٰٓ
Transliteration: AAabasa watawalla
Translation: Ó fajú ro, ó sì pẹ̀yìndà1
عَبَسَ وَتَوَلَّىٰٓ ﴿1﴾عَبَسَ وَتَوَلَّىٰٓ
Transliteration: AAabasa watawalla
Translation: Ó fajú ro, ó sì pẹ̀yìndà1
أَن جَآءَهُ ٱلۡأَعۡمَىٰ ﴿2﴾أَن جَآءَهُ ٱلۡأَعۡمَىٰ
Transliteration: An jaahu alaAAma
Translation: nítorí pé afọ́jú wá bá a.
وَمَا يُدۡرِيكَ لَعَلَّهُۥ يَزَّكَّىٰٓ ﴿3﴾وَمَا يُدۡرِيكَ لَعَلَّهُۥ يَزَّكَّىٰٓ
Transliteration: Wama yudreeka laAAallahu yazzakka
Translation: Kí sì l’ó máa fi mọ̀ ọ́ pé ó ṣeé ṣe kí ó ṣàfọ̀mọ́ (ara rẹ̀ kúrò nínú àìgbàgbọ́)
أَوۡ يَذَّكَّرُ فَتَنفَعَهُ ٱلذِّكۡرَىٰٓ ﴿4﴾أَوۡ يَذَّكَّرُ فَتَنفَعَهُ ٱلذِّكۡرَىٰٓ
Transliteration: Aw yaththakkaru fatanfaAAahu alththikra
Translation: tàbí kí ó gbọ́ ìrántí, kí ìrántí náà sì ṣe é ní àǹfààní?
أَمَّا مَنِ ٱسۡتَغۡنَىٰ ﴿5﴾أَمَّا مَنِ ٱسۡتَغۡنَىٰ
Transliteration: Amma mani istaghna
Translation: Ní ti ẹni tí ó ka ara rẹ̀ kún ọlọ́rọ̀,
فَأَنتَ لَهُۥ تَصَدَّىٰ ﴿6﴾فَأَنتَ لَهُۥ تَصَدَّىٰ
Transliteration: Faanta lahu tasadda
Translation: òun ni ìwọ tẹ́tí sí.
وَمَا عَلَيۡكَ أَلَّا يَزَّكَّىٰ ﴿7﴾وَمَا عَلَيۡكَ أَلَّا يَزَّكَّىٰ
Transliteration: Wama AAalayka alla yazzakka
Translation: Kò sì sí ẹ̀ṣẹ̀ fún ọ bí kò bá ṣe àfọ̀mọ́ (ara rẹ̀ kúrò nínú àìgbàgbọ́).
وَأَمَّا مَن جَآءَكَ يَسۡعَىٰ ﴿8﴾وَأَمَّا مَن جَآءَكَ يَسۡعَىٰ
Transliteration: Waamma man jaaka yasAAa
Translation: Ní ti ẹni tí ó sì wá bá ọ, tó ń yára gágá (sí ìrántí, ìyẹn afọ́jú),
وَهُوَ يَخۡشَىٰ ﴿9﴾وَهُوَ يَخۡشَىٰ
Transliteration: Wahuwa yakhsha
Translation: tí ó sì ń páyà (Allāhu),
فَأَنتَ عَنۡهُ تَلَهَّىٰ ﴿10﴾فَأَنتَ عَنۡهُ تَلَهَّىٰ
Transliteration: Faanta AAanhu talahha
Translation: ìwọ kò sì kọbi ara sí i.
كَلَّآ إِنَّهَا تَذۡكِرَةٞ ﴿11﴾كَلَّآ إِنَّهَا تَذۡكِرَةٞ
Transliteration: Kalla innaha tathkiratun
Translation: Rárá (kò tọ́ bẹ́ẹ̀). Dájúdájú al-Ƙur’ān ni ìrántí.
فَمَن شَآءَ ذَكَرَهُۥ ﴿12﴾فَمَن شَآءَ ذَكَرَهُۥ
Transliteration: Faman shaa thakarahu
Translation: Nítorí náà, ẹni tí ó bá fẹ́ kí ó rántí rẹ̀.
فِي صُحُفٖ مُّكَرَّمَةٖ ﴿13﴾فِي صُحُفٖ مُّكَرَّمَةٖ
Transliteration: Fee suhufin mukarramatin
Translation: (Al-Ƙur’ān) wà nínú àwọn tàkádà alápọ̀n-ọ́nlé,
مَّرۡفُوعَةٖ مُّطَهَّرَةِۭ ﴿14﴾مَّرۡفُوعَةٖ مُّطَهَّرَةِۭ
Transliteration: MarfooAAatin mutahharatin
Translation: A gbé e ga, A sì ṣe é ní mímọ́
بِأَيۡدِي سَفَرَةٖ ﴿15﴾بِأَيۡدِي سَفَرَةٖ
Transliteration: Biaydee safaratin
Translation: ní ọwọ́ àwọn òǹkọtíà (ìyẹn, àwọn mọlāika),
كِرَامِۭ بَرَرَةٖ ﴿16﴾كِرَامِۭ بَرَرَةٖ
Transliteration: Kiramin bararatin
Translation: àwọn alápọ̀n-ọ́nlé, àwọn ẹni rere.
قُتِلَ ٱلۡإِنسَٰنُ مَآ أَكۡفَرَهُۥ ﴿17﴾قُتِلَ ٱلۡإِنسَٰنُ مَآ أَكۡفَرَهُۥ
Transliteration: Qutila alinsanu ma akfarahu
Translation: Wọ́n ti fi ènìyàn gégùn-ún (nípa) bí ó ṣe jẹ́ aláìmoore jùlọ!
مِنۡ أَيِّ شَيۡءٍ خَلَقَهُۥ ﴿18﴾مِنۡ أَيِّ شَيۡءٍ خَلَقَهُۥ
Transliteration: Min ayyi shayin khalaqahu
Translation: Kí sì ni Allāhu fi ṣẹ̀dá rẹ̀?
مِن نُّطۡفَةٍ خَلَقَهُۥ فَقَدَّرَهُۥ ﴿19﴾مِن نُّطۡفَةٍ خَلَقَهُۥ فَقَدَّرَهُۥ
Transliteration: Min nutfatin khalaqahu faqaddarahu
Translation: Nínú àtọ̀ l’Ó ti ṣẹ̀dá rẹ̀. Ó sì pèbùbù (ẹ̀yà-ara) rẹ̀.
ثُمَّ ٱلسَّبِيلَ يَسَّرَهُۥ ﴿20﴾ثُمَّ ٱلسَّبِيلَ يَسَّرَهُۥ
Transliteration: Thumma alssabeela yassarahu
Translation: Lẹ́yìn náà, Ó ṣe ọ̀nà àtiwáyé ní ìrọ̀rùn fún un.
ثُمَّ أَمَاتَهُۥ فَأَقۡبَرَهُۥ ﴿21﴾ثُمَّ أَمَاتَهُۥ فَأَقۡبَرَهُۥ
Transliteration: Thumma amatahu faaqbarahu
Translation: Lẹ́yìn náà, Ó máa pa á. Ó sì máa fi sínú sàréè.
ثُمَّ إِذَا شَآءَ أَنشَرَهُۥ ﴿22﴾ثُمَّ إِذَا شَآءَ أَنشَرَهُۥ
Transliteration: Thumma itha shaa ansharahu
Translation: Lẹ́yìn náà, nígbà tí Allāhu bá fẹ́, Ó máa gbé e dìde.
كَلَّا لَمَّا يَقۡضِ مَآ أَمَرَهُۥ ﴿23﴾كَلَّا لَمَّا يَقۡضِ مَآ أَمَرَهُۥ
Transliteration: Kalla lamma yaqdi ma amarahu
Translation: Rárá o! Ènìyàn kò tí ì ṣe n̄ǹkan tí Allāhu pa láṣẹ fún un.
فَلۡيَنظُرِ ٱلۡإِنسَٰنُ إِلَىٰ طَعَامِهِۦٓ ﴿24﴾فَلۡيَنظُرِ ٱلۡإِنسَٰنُ إِلَىٰ طَعَامِهِۦٓ
Transliteration: Falyanthuri alinsanu ila taAAamihi
Translation: Nítorí náà, kí ènìyàn wòye sí oúnjẹ rẹ̀.
أَنَّا صَبَبۡنَا ٱلۡمَآءَ صَبّٗا ﴿25﴾أَنَّا صَبَبۡنَا ٱلۡمَآءَ صَبّٗا
Transliteration: Anna sababna almaa sabban
Translation: Dájúdájú Àwa ń rọ òjò ní púpọ̀.
ثُمَّ شَقَقۡنَا ٱلۡأَرۡضَ شَقّٗا ﴿26﴾ثُمَّ شَقَقۡنَا ٱلۡأَرۡضَ شَقّٗا
Transliteration: Thumma shaqaqna alarda shaqqan
Translation: Lẹ́yìn náà, A mú ilẹ̀ sán kànkàn.
فَأَنۢبَتۡنَا فِيهَا حَبّٗا ﴿27﴾فَأَنۢبَتۡنَا فِيهَا حَبّٗا
Transliteration: Faanbatna feeha habban
Translation: A sì mú kóró èso hù jáde láti inú rẹ̀;
وَعِنَبٗا وَقَضۡبٗا ﴿28﴾وَعِنَبٗا وَقَضۡبٗا
Transliteration: WaAAinaban waqadban
Translation: àti èso àjàrà àti kànnáfùrù,
وَزَيۡتُونٗا وَنَخۡلٗا ﴿29﴾وَزَيۡتُونٗا وَنَخۡلٗا
Transliteration: Wazaytoonan wanakhlan
Translation: àti igi òróró Zaetūn àti dàbínù,
وَحَدَآئِقَ غُلۡبٗا ﴿30﴾وَحَدَآئِقَ غُلۡبٗا
Transliteration: Wahadaiqa ghulban
Translation: àti àwọn ọgbà tó kún fún igi,
وَفَٰكِهَةٗ وَأَبّٗا ﴿31﴾وَفَٰكِهَةٗ وَأَبّٗا
Transliteration: Wafakihatan waabban
Translation: àti àwọn èso (mìíràn) pẹ̀lú ewé tí ẹranko ń jẹ, (A mú wọn hù jáde).
مَّتَٰعٗا لَّكُمۡ وَلِأَنۡعَٰمِكُمۡ ﴿32﴾مَّتَٰعٗا لَّكُمۡ وَلِأَنۡعَٰمِكُمۡ
Transliteration: MataAAan lakum walianAAamikum
Translation: (Wọ́n jẹ́ n̄ǹkan) ìgbádùn fún ẹ̀yin àti àwọn ẹran-ọ̀sìn yín.
فَإِذَا جَآءَتِ ٱلصَّآخَّةُ ﴿33﴾فَإِذَا جَآءَتِ ٱلصَّآخَّةُ
Transliteration: Faitha jaati alssakhkhatu
Translation: Nígbà tí fífọn sínú ìwo nígbà kejì bá ṣẹlẹ̀,
يَوۡمَ يَفِرُّ ٱلۡمَرۡءُ مِنۡ أَخِيهِ ﴿34﴾يَوۡمَ يَفِرُّ ٱلۡمَرۡءُ مِنۡ أَخِيهِ
Transliteration: Yawma yafirru almaro min akheehi
Translation: ní ọjọ́ tí ènìyàn yóò sá fún arákùnrin rẹ̀,
وَأُمِّهِۦ وَأَبِيهِ ﴿35﴾وَأُمِّهِۦ وَأَبِيهِ
Transliteration: Waommihi waabeehi
Translation: àti ìyá rẹ̀ àti bàbá rẹ̀,
وَصَٰحِبَتِهِۦ وَبَنِيهِ ﴿36﴾وَصَٰحِبَتِهِۦ وَبَنِيهِ
Transliteration: Wasahibatihi wabaneehi
Translation: àti ìyàwó rẹ̀ àti àwọn ọmọ rẹ̀.
لِكُلِّ ٱمۡرِيٕٖ مِّنۡهُمۡ يَوۡمَئِذٖ شَأۡنٞ يُغۡنِيهِ ﴿37﴾لِكُلِّ ٱمۡرِيٕٖ مِّنۡهُمۡ يَوۡمَئِذٖ شَأۡنٞ يُغۡنِيهِ
Transliteration: Likulli imriin minhum yawmaithin shanun yughneehi
Translation: Ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn ní ọjọ́ yẹn l’ó ti ní ọ̀ràn tó máa tó o ó rán.
وُجُوهٞ يَوۡمَئِذٖ مُّسۡفِرَةٞ ﴿38﴾وُجُوهٞ يَوۡمَئِذٖ مُّسۡفِرَةٞ
Transliteration: Wujoohun yawmaithin musfiratun
Translation: Àwọn ojú kan lọ́jọ́ yẹn yóò mọ́lẹ̀.
ضَاحِكَةٞ مُّسۡتَبۡشِرَةٞ ﴿39﴾ضَاحِكَةٞ مُّسۡتَبۡشِرَةٞ
Transliteration: Dahikatun mustabshiratun
Translation: Wọn yó máa rẹ́rìn-ín, wọn yó sì máa dunnú.
وَوُجُوهٞ يَوۡمَئِذٍ عَلَيۡهَا غَبَرَةٞ ﴿40﴾وَوُجُوهٞ يَوۡمَئِذٍ عَلَيۡهَا غَبَرَةٞ
Transliteration: Wawujoohun yawmaithin AAalayha ghabaratun
Translation: Àwọn ojú kan lọ́jọ́ yẹn ni eruku yó sì bò mọ́lẹ̀.
تَرۡهَقُهَا قَتَرَةٌ ﴿41﴾تَرۡهَقُهَا قَتَرَةٌ
Transliteration: Tarhaquha qataratun
Translation: Òkùnkùn yó sì bò wọ́n mọ́lẹ̀.
أُوْلَـٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡكَفَرَةُ ٱلۡفَجَرَةُ ﴿42﴾أُوْلَـٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡكَفَرَةُ ٱلۡفَجَرَةُ
Transliteration: Olaika humu alkafaratu alfajaratu
Translation: Àwọn wọ̀nyẹn gan-an ni aláìgbàgbọ́, ẹlẹ́ṣẹ̀.
Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download