أَرَءَيۡتَ ٱلَّذِي يُكَذِّبُ بِٱلدِّينِ ﴿1﴾أَرَءَيۡتَ ٱلَّذِي يُكَذِّبُ بِٱلدِّينِ
Transliteration: Araayta allathee yukaththibu bialddeeni
Translation: Sọ fún mi nípa ẹni tó ń pe Ọjọ́ Ẹ̀san ní irọ́!
أَرَءَيۡتَ ٱلَّذِي يُكَذِّبُ بِٱلدِّينِ ﴿1﴾أَرَءَيۡتَ ٱلَّذِي يُكَذِّبُ بِٱلدِّينِ
Transliteration: Araayta allathee yukaththibu bialddeeni
Translation: Sọ fún mi nípa ẹni tó ń pe Ọjọ́ Ẹ̀san ní irọ́!
فَذَٰلِكَ ٱلَّذِي يَدُعُّ ٱلۡيَتِيمَ ﴿2﴾فَذَٰلِكَ ٱلَّذِي يَدُعُّ ٱلۡيَتِيمَ
Transliteration: Fathalika allathee yaduAAAAu alyateema
Translation: Ìyẹn ni ẹni tó ń lé ọmọ-òrukàn dànù.
وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ ٱلۡمِسۡكِينِ ﴿3﴾وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ ٱلۡمِسۡكِينِ
Transliteration: Wala yahuddu AAala taAAami almiskeeni
Translation: Kò sì níí gbìyànjú láti bọ́ mẹ̀kúnnù.
فَوَيۡلٞ لِّلۡمُصَلِّينَ ﴿4﴾فَوَيۡلٞ لِّلۡمُصَلِّينَ
Transliteration: Fawaylun lilmusalleena
Translation: Ègbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) tó ń kírun;1
ٱلَّذِينَ هُمۡ عَن صَلَاتِهِمۡ سَاهُونَ ﴿5﴾ٱلَّذِينَ هُمۡ عَن صَلَاتِهِمۡ سَاهُونَ
Transliteration: Allatheena hum AAan salatihim sahoona
Translation: àwọn tó ń gbàgbé láti kírun wọn ní àsìkò rẹ̀;
ٱلَّذِينَ هُمۡ يُرَآءُونَ ﴿6﴾ٱلَّذِينَ هُمۡ يُرَآءُونَ
Transliteration: Allatheena hum yuraoona
Translation: àwọn tó ń ṣe ṣekárími;
وَيَمۡنَعُونَ ٱلۡمَاعُونَ ﴿7﴾وَيَمۡنَعُونَ ٱلۡمَاعُونَ
Transliteration: WayamnaAAoona almaAAoona
Translation: àti pé wọ́n ń hánnà ohun èlò (fún àwọn ènìyàn).
Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download