quranm◉

Surah At-Takathur transliteration

◉ Súrá · ∞

102:1

أَلۡهَىٰكُمُ ٱلتَّكَاثُرُ ﴿1﴾

Transliteration: Alhakumu alttakathuru

Translation: Wíwá oore ayé ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ fún ìyanràn ṣíṣe ti kó àìrójú fẹ́sìn ba yín

102:2

حَتَّىٰ زُرۡتُمُ ٱلۡمَقَابِرَ ﴿2﴾

Transliteration: Hatta zurtumu almaqabira

Translation: títí ẹ fi wọ inú sàréè.

102:3

كَلَّا سَوۡفَ تَعۡلَمُونَ ﴿3﴾

Transliteration: Kalla sawfa taAAlamoona

Translation: Rárá (kò yẹ kó rí bẹ́ẹ̀, àmọ́) láìpẹ́ ẹ máa mọ̀.

102:4

ثُمَّ كَلَّا سَوۡفَ تَعۡلَمُونَ ﴿4﴾

Transliteration: Thumma kalla sawfa taAAlamoona

Translation: Lẹ́yìn náà, ní ti òdodo, láìpẹ́ ẹ máa mọ̀.

102:5

كَلَّا لَوۡ تَعۡلَمُونَ عِلۡمَ ٱلۡيَقِينِ ﴿5﴾

Transliteration: Kalla law taAAlamoona AAilma alyaqeeni

Translation: Ní ti òdodo, tí ó bá jẹ́ pé ẹ ni ìmọ̀ àmọ̀dájú ni (ẹ̀yin ìbá tí ṣe bẹ́ẹ̀).

102:6

لَتَرَوُنَّ ٱلۡجَحِيمَ ﴿6﴾

Transliteration: Latarawunna aljaheema

Translation: Dájúdájú ẹ máa rí iná Jẹhīm.

102:7

ثُمَّ لَتَرَوُنَّهَا عَيۡنَ ٱلۡيَقِينِ ﴿7﴾

Transliteration: Thumma latarawunnaha AAayna alyaqeeni

Translation: Lẹ́yìn náà, dájúdájú ẹ máa fi ojú rí i ní àrídájú.

102:8

ثُمَّ لَتُسۡـَٔلُنَّ يَوۡمَئِذٍ عَنِ ٱلنَّعِيمِ ﴿8﴾

Transliteration: Thumma latusalunna yawmaithin AAani alnnaAAeemi

Translation: Lẹ́yìn náà, dájúdájú ní ọjọ́ yẹn wọ́n máa bi yín léèrè nípa ìgbádùn (ayé yìí).

Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download