تَبَّتۡ يَدَآ أَبِي لَهَبٖ وَتَبَّ ﴿1﴾تَبَّتۡ يَدَآ أَبِي لَهَبٖ وَتَبَّ
Transliteration: Tabbat yada abee lahabin watabba
Translation: Ọwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò.
تَبَّتۡ يَدَآ أَبِي لَهَبٖ وَتَبَّ ﴿1﴾تَبَّتۡ يَدَآ أَبِي لَهَبٖ وَتَبَّ
Transliteration: Tabbat yada abee lahabin watabba
Translation: Ọwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò.
مَآ أَغۡنَىٰ عَنۡهُ مَالُهُۥ وَمَا كَسَبَ ﴿2﴾مَآ أَغۡنَىٰ عَنۡهُ مَالُهُۥ وَمَا كَسَبَ
Transliteration: Ma aghna AAanhu maluhu wama kasaba
Translation: Àwọn dúkìá rẹ̀ àti ohun tí ó ṣe níṣẹ́ (ìyẹn, àwọn ọmọ rẹ̀) kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ (níbi ìyà).
سَيَصۡلَىٰ نَارٗا ذَاتَ لَهَبٖ ﴿3﴾سَيَصۡلَىٰ نَارٗا ذَاتَ لَهَبٖ
Transliteration: Sayasla naran thata lahabin
Translation: Ó sì máa wọ inú Iná eléjò fòfò.
وَٱمۡرَأَتُهُۥ حَمَّالَةَ ٱلۡحَطَبِ ﴿4﴾وَٱمۡرَأَتُهُۥ حَمَّالَةَ ٱلۡحَطَبِ
Transliteration: Waimraatuhu hammalata alhatabi
Translation: Àti ìyàwó rẹ̀, aláàárù-igi-ìṣẹ́pẹ́ ẹlẹ́gùn-ún, (ó máa wọná).
فِي جِيدِهَا حَبۡلٞ مِّن مَّسَدِۭ ﴿5﴾فِي جِيدِهَا حَبۡلٞ مِّن مَّسَدِۭ
Transliteration: Fee jeediha hablun min masadin
Translation: Igbà-ọ̀pẹ pọ̀npọ̀nràn máa wà ní ọrùn rẹ̀ (nínú Iná).
Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download