quranm◉

Surah An-Nas transliteration

◉ Súrá · ∞

114:1

قُلۡ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلنَّاسِ ﴿1﴾

Transliteration: Qul aAAoothu birabbi alnnasi

Translation: Sọ pé: “Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,

114:2

مَلِكِ ٱلنَّاسِ ﴿2﴾

Transliteration: Maliki alnnasi

Translation: Ọba àwọn ènìyàn,

114:3

إِلَٰهِ ٱلنَّاسِ ﴿3﴾

Transliteration: Ilahi alnnasi

Translation: Ọlọ́hun àwọn ènìyàn,1

114:4

مِن شَرِّ ٱلۡوَسۡوَاسِ ٱلۡخَنَّاسِ ﴿4﴾

Transliteration: Min sharri alwaswasi alkhannasi

Translation: níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni tó bá ń dárúkọ Allāhu.

114:5

ٱلَّذِي يُوَسۡوِسُ فِي صُدُورِ ٱلنَّاسِ ﴿5﴾

Transliteration: Allathee yuwaswisu fee sudoori alnnasi

Translation: (Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.

114:6

مِنَ ٱلۡجِنَّةِ وَٱلنَّاسِ ﴿6﴾

Transliteration: Mina aljinnati wa alnnasm

Translation: (Èṣù náà) wà nínú àwọn àlùjànnú àti àwọn ènìyàn.”

Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download