quranm◉

Surah Al-Kafirun transliteration

◉ Súrá · ∞

109:1

قُلۡ يَـٰٓأَيُّهَا ٱلۡكَٰفِرُونَ ﴿1﴾

Transliteration: Qul ya ayyuha alkafiroona

Translation: Sọ pé: “Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́,

109:2

لَآ أَعۡبُدُ مَا تَعۡبُدُونَ ﴿2﴾

Transliteration: La aAAbudu ma taAAbudoona

Translation: Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún.

109:3

وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ ﴿3﴾

Transliteration: Wala antum AAabidoona ma aAAbudu

Translation: Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.

109:4

وَلَآ أَنَا۠ عَابِدٞ مَّا عَبَدتُّمۡ ﴿4﴾

Transliteration: Wala ana AAabidun ma AAabadtum

Translation: Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́.

109:5

وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ ﴿5﴾

Transliteration: Wala antum AAabidoona ma aAAbudu

Translation: Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.

109:6

لَكُمۡ دِينُكُمۡ وَلِيَ دِينِ ﴿6﴾

Transliteration: Lakum deenukum waliya deeni

Translation: Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi.”

Transliteration source: English Transliteration by Tanzil. Used under Tanzil's non-commercial terms; see the source and latest updates at Tanzil. Tanzil translation download